NIGERIA GBODO NA ZAMBIA TABI GBA DRAW NI WORLD CUP QUALIFIER

  Alex-Iwobi-and-Kelechi-Iheanacho-orisun

  NIGERIA GBODO NA ZAMBIA TABI GBA DRAW NI WORLD CUP QUALIFIER

  Super Eagles ti ilu Nigeria ma gba boolu idije ese keta (3rd round) world cup qualifier pelu egbe agbaboolu Chipolopolo ti ilu zambia ni papa isere (stadium) Uyo ni October 7th, 2017 ni dede ago marun.

  Awon atokun wa lori eto Bosenlo Sports ri si oro idije boolu laarin Super Eagles ati Chipolopolo of Zambia ni Saturday, E wo nkan ti won so ninu fidio yii….

   

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here