Lagbo Oṣelu Pẹlu Oludije Du’po Igbakeji Gomina Ipinlẹ Ogun ANRP, Mrs. Olusesan

  Powerful-women-in-buhari-government-politic-ibo-iselu-oselu

  Lagbo Oṣelu Pẹlu Oludije Du’po Igbakeji Gomina Ipinlẹ Ogun ANRP, Mrs. Olusesan

  Oludije du ipo igbakeji gomina ipinlẹ ogun ni alejo wa lori eto Lagbo oṣelu ti saa yii.

  Lori eto yii, Adedire ati Kunle Fasugba sọrọ lori ipa ti awọn eniyan n ko ni igba eto idibo ni Nigeria; paapajulọ awọn Obinrin.

  NJẸ O DARA KI OBINRIN MAA JADE DU IPO?

  Iru ibeere yii ati awọn omiran ni a bi Mrs Adenokun Risikat Oluṣesan ti o fẹ du ipo igbakeji gomina ni ipinlẹ Ogun nibi eto idibo ti o n bọ.

  Ẹ wo fidio ti o wa ni isalẹ yii lati gbadun Eto naa.

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here