
IRU OUNJE TO DA FUN ENI T’ONI STOMACH ULCER

Stomach Ulcer je arun ti o ma je yo ni inu ikun omo eniyan ti a ko ba se awon nkan ti o ye ki a se. Ni opo igba ni awon ti o ba ni Stomach Ulcer o kin mo iru ounje ti o ye ki won ma je, Opo igbe ni won ma n ri wipe awon n je awon ounje ti o ye ki awon ti o ni Stomach Ulcer ye ki won maa je…
Kini iru awon ounje ti o ye ki eni ti o ni Stomach Ulcer maa je? E wo ninu fidio oke yen….
E TUN LE KA: Orisirisi Aisan Ti O Wa Ninu Enu Yato Si Oorun Enu
E TUN LE WO: