Ipo Awọn Obinrin Ninu Eto Iṣelu Ni Orilẹ Ede Nigeria

  Ipo Awọn Obinrin Ninu Eto Iṣelu Ni Orilẹ Ede Nigeria

  Lori eto B’osenlọ ni Orisun tẹlifisan ni a ti n jiroro lori awọn ipa ti awọn obinrin n ko ninu eto Iṣelu ni Orilẹ ede yii.

  Gẹgẹ bi a ti mọ wipe awọn obinrin jẹ igi lẹyin ọgba awọn ọkunrin sugbọn ni aye atijọ n a ti mọ wipe ‘yara ounjẹ ni ofiisi wọn wa. Sugbọn laye ode oni, awọn Obinrin ti n gbe ileaye ṣe nnkan miran ti o yẹ ki ọkunrin maa ṣe. Obinrin ni a gbọ wipe o n ṣe Sobata, ni o ṣe Gomina orilẹ ipinlẹ, ni o n dari ijọ laarin awọn kristẹni ati bẹẹbẹẹ lọ ninu awọn ohun ti obinrin n ṣe.

  Ẹ gbọ ohun ti awọn atọkun eto wa Adedire ati akẹgbẹ re sọ nipa Ipo awọn obinrin gẹgẹ bi oṣelu.

   

  Leave a Reply