Idi Ti Nigeria O Se Ni Isokan (Unity)

  Idi Ti Nigeria O Se Ni Isokan (Unity)

  Nigeria je orile ede ti o kun opo eya eniyan ti o n gbe ni gbogbo rikerike agbegbe re. Nigeria pin si origun merin ti a n pe ni Ila oorun, Iwo oorun, Guusu ati Ariwa.  Lati Igba ti orile ede nigeria ti gba ominira lowo awon oyinbo, ise nla ni o je fun awon ijoba wa lati mu gbogbo origun orileede yi wa ni isokan (Unity). Opo Aare teletele ri lo ti gbiyanju lati mu iwa lekanka kuro ni aarin awon ara ilu. Kini Nkan ti o n fa a si Isokan? Kini idi ti nigeria o se si ni isokan (unity)?

  E TUN LE KA: Ipinle To Ni Iwa Jegudujera Ju Ni Nigeria

  E wo Loke>>>

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here