#Bosenlo: Nkan Ti A Le Se Ti Tyre Moto Ba Baje

  #Bosenlo: Nkan Ti A Le Se Ti Tyre Moto Ba Baje

  Cars ti a n pe ni moto tabi oko je nkan ti o le daku ni igbakugba lai fi ami han pe ohun yoo da ise sile, eyi ti o je pe a le pe atun oko se iyen Mechanic pe ki o wa tun se. A mo ki laa se ti oko ba wa ni ori express tabi ona ti o jin si Mechanic? Opo eyan ni o mo ogbon ti won le da si oko ti o ba yonu. Lori eto Bosenlo, a o soro nipa bi a se le tun awon nkan kekeeke se ninu oko lati ori Tyre oko….

  E TUN LE WO:Ise Aiye Ko Lo N Fa Aisan Warapa

  E wo ba yi>>>

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here