BI A SE LE SE ITOJU OMO TO BA NI MEASLES

  BI A SE LE SE ITOJU OMO TO BA NI MEASLES

  MEASLES je okan lara awon arun buruku ti o ma n se okunfa opolopo iku omode ati agbalagba ni orile ede Nigeria. Awon ti o ma n kan agbake Arun Measles yi ma n ko lati ofurufuru (air) latari iko (cough) ati sinsin (sneeze) lati odo awon ti o ti ni tele.

  Ti eeyan ba ti ni aarun Measles, Ona wo la legba toju iru eeyan bee, e wo fidio yi nibiti sekinat ati alejo re ti n yannanna akori yi….

   

   

  E TUN LE WO:

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here