Awon Aanfani Keke Marwa Yato Si Moto Tabi Okada

    Awon Aanfani Keke Marwa Yato Si Moto Tabi Okada

    Keke Marwa je oko elese meta ti won fi n se kabu kabu kaakiri ilu nigeria ni eyin igba ti won gbe opa ijoba le okada. Lati igba ti won si ti bere ise ni inu ilu ni awon eyan ti n soro nipa e kakaakiri ti won si fi n sise je. kini anfani keke maruwa si awujo wa? kini awon ere ti o wa ninu wiwa keke maruwa? iha wo ni ijoba ko si keke maruwa?

    E TUN WO: #Bosenlo: Nkan Ti A Le Se Ti Tyre Moto Ba Baje

    E wo ni bi yii>>>>

    Leave a Reply