Ami Ti O Maa N Jeyo Lara Eni Ti O Fe Ni Arun Warapa

  Ami Ti O Maa N Jeyo Lara Eni Ti O Fe Ni Arun Warapa

  Epilepsy (Warapa) je arun opolo (brain) ti o ma n je latari wipe opolo ti n sise pupoju… Awon ami ti o maa n jeyo lara eni ti o fe ni arun warapa. E wo fidio yii ki e le gbo alaye lori eto Bosenlo labala ilera.Lori eto Bosenlo ti Ilera ara wa pelu Alice ati Sekinat  to ni aisan yi….

  E TUN LE WO:Ise Aiye Ko Lo N Fa Aisan Warapa

  E wo ni bi yii>>

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here