Skip to content

Biodun Okeowo s’oro leyin ti won ji iPhone 7 e

Osere ‘binrin, Biodun Okeowo s’oro leyin ti eyan kan ji iPhone 7 e

Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji.

Gege bi osere naa se so, ero ibanisoro naa se Pataki lopolopo nitori awon nkan ti o se iyebiye wa ninu aago naa.

E tun le ka: Toyosi gba awon obirin ni amoran lori awon okunrin

Nkan ti o ko ree;

“My Rose gold plated IPhone 7plus was stolen at a party in Ikeja today, please kindly get in touch if you have any information or you sight anyone trying to sell a used IPhone 7plus at Computer Village, I will compensate the person in a big way, this phone is very important to me, it contains vital informations and documents, it is one of my business lines.
Thanks love you all.
Biodun Okeowo.”

 

Aworan naa re:

Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji.