Skip to content

Bi Won Se N Se Eto Igbeyawo Ni Ile Yoruba

Marriage (igbeyawo) ni ile yoruba,  je nkan pataki; o je nkan iwuri.MArriage (igbeyawo) ti won n se ni aye atijo ti yato si bi won ti n se ni aye isin leyi ti o tii di aye olaju… Bawo ni won se n se ni aye atijo? Kini awon elo ti won lo?

E TUN LE KA: Igbese Akoko Ti O Ye Ka Gbe Fun Eto Ayeye IGBEYAWO

Ninu fidio yii won ya-na-naa awon nkan ti won se ni ibi igbeyawo ati awon ohun elo.

E TUN LE WO: