Skip to content

BI A SE LE YO LAALI KURO LOWO

Laali je nkan ase ara looge ti o wa lati ilu india ti o fi wa di pe o wopo ni Nigeria paapaa julo ni ile hausa… Opo awon obirin isinyin ni won ma n feran lati se laali si owo tabi eekanna owo ati ese papa julo ni ojo igbeyawo… Bi oge laali se rewa to, o ma n pe ki o to kuro ni ara eyi ti o je idi ti awon omiran fi feran re sugbon awon eyan ma n fe yoo kuro ni arawon ni kia kia…

E TUN LE KA:Osere Bimbo Thomas Fi Aworan Omo Re Yangan

Ni ori eto Ojumo Ire pelu atokun Olatorera, alejo re soro nipa bi a se le yo laali kuro ni lara ati bi won se le se laali ki o ma pe ki o to kuro…..

 

E TUN WO: