Hajj je okan ninu awon opo islam ti o si je oranyan fun gbogbo musulumi ti o ba ti ni agbara lati se. Riran omo iya wa ninu islam lo si hajj ni lada pupo ti won ba se e daadaa sugbon opo igba ni gbogbo awon ti won ran eniyan lo si hajj o mo kule kule ohun ti o ye kan she ti won fi le gba lada kikun….
Alfa Owo Adua yan nana bi a se le gbe gba ati gbogbo nkan ti o ye ki won se lori Ojumo Ire.
E TUN LE WO:Eekan ni Hajj Lilo Je Oranyan fun gbogbo Musulumi
E wo ni bi yii>>>