Ero ayelujara ni nkan ti gbogbo eniyan nlo ni gbogbo agbanlaiye yala okunrin, obirin tabi omode. Ni aye ode isinyi, orisirisi nkan lo wa lori ero ayelujara won yi yala facebook, instagram,twitter,youtube, snapchat atibeebeelo. Opolopo igba ni ero ayelujara yi ti fa ede aiyede ati wahala laarin awon eniyan bee lo ti si se nkan daadaa lolokanojokan….
Lori eto Ojumo ire pelu ATABATUBU ati OLORI KEMI, won soro nipa bi ati le dekun ilo ero ayelujara ni ona aito pelu alejo won Omooba Adesuyi Oluwadamilare
E TUN LE WO: Eekan ni Hajj Lilo Je Oranyan fun gbogbo Musulumi
E wo ni bi yii>>>>