Skip to content

Bi Ruggedman Se Se Ayeye Ojo Ibi Re

Olorin Ruggedman se ojo ibi re ni september 20th, 2017 ti o si se ayeye ojo ibi re pelu ore ati ojulumo. Ni akoko, Ruggedman se ayeye ojo ibi re ni Abuja pelu ore re aderinposhonu klint da drunk, ki o to gbe gbogbo poposhinshin ayeye naa wa ssi eko ni club rumors ni victoria island. Gegebi eti mo, awon ilumooka yapa si ibi ayeye naa bi juliet ibrahim, iceberg slim, coco ice, azadus atibeebeelo… Awon aworan lati ibi ayeye naa re…

E TUN LE KA: King Sunny Ade Pe 77yrs Ni Oni, E Ki Won Ku Orire

 

ruggedman-orisun

ruggedman-orisun

ruggedman-orisun

ruggedman-orisun

ruggedman-orisun

ruggedman-orisun