Bi Fayemi Se Ja Ilu EKiti lole – IGBIMO IWADI
Iroyin ti o n de si eti igbo wa losan oni ni wipe Ajo Idajo Ati Iwadi ti ilu ekiti gbe kale lati seto lori inadura labe ijoba Kayode Fayemi ti o je gomina teleri ti pariwo sita wipe, Gomina teleri naa gbodo se awari iye owo N2.75 Billionu naira ti won yo ninu N25 billion ti won gba lowo ijoba apapo fun kiko Oja Nla ‘Ultra-Modern Market’ si ilu Ado-Ekiti ti won ko pada se.
Ajo ti o n se iwadi baa so fun agbases ti won gba lati tun Ibi ise ati ile ijoba (government house) ti Fayemu n gbe; ki o da iye Owo N324.8millionu naira bi won ti so wipe iye owo fun use baa ko ye ko ju bi N280 milionu naira lo.
IDI TI AWON ALASE CITY PEOPLE AWARDS SE PIN AYEYE WON KELEKELE
Igbimo fun iwadi naa ri asiri kan nipa KITWOOD NIGERIA LIMITED ti o gba ise itoju Ile Ijoba naa gba N600 iye millionu ti ko si ni adireesi kankan ti won si ti gbe owo naa fun-un, adireesi ti won fi sibi je ile ti won ko tii kole si eyi ti o wa ni agbegbe Central Bank ni ona Iyin ni ilu Ado Ekiti.
Asiri yii ati omiran ni o jade loni ojo’bo nigba ti Igbimo ti o n wadi naa gbe ejo naa lo s’odo Gomina tuntun; iyen Governor Ayodele Fayose ti Ogbeni Silas Oyewole si je Adari igbimo naa.
Igbimo naa so wipe, nigbati Ijoba Fayemi yoo ra Moto, Ileese Coscharis ni o gbe iye oko ojilenigba din marun si òjìlénígba lé mewaa Oko ayokele ati boosi wipe o ja ijoba lole ti o si gbe wahala si agbada ijoba naa.
E Wo Nnkan Ti Ero AyarabiAsa Google Se Si Awon Orin Davido
Gebe bi won ti wi ni ede geesi;
“That Coscharis Motors supplied some vehicles outside Ekiti State especially, at Ibadan Liaison office when Ekiti State Government does not have a Liaison office in Ibadan. In respect of this, seven vehicles were supplied outside the State and signed for by unknown persons.
“That Coscharis Motors only supplied 219 vehicles to the Ekiti State government and that 17 Joylong Buses were supplied to the Ekiti State Government as gift but later carted away.”
Awon nnkan miran wa ti ko tii tu sita bi won ti so fun awon oniroyin sugbon bi o ba se n jade ni o maa fi too yin leti.