Skip to content

BBNaija Winner Efe Bere Ere Nollywood

BBNaija winner ti odun 2017, Efe Ejeba, ti gba amoran awon fans e lati se nkan omiran yato si orin. Oti wa gbe igbese si ona Nollywood lati bere si ni ma se ere agbelewo. O so eleyi di mimo ni ori ero abanidore instagram pelu awon aworan yi. akole ere naa ni WAWU ti o si ri bi M Ibu, Daddy Showkey ati aderinposonu Helen paul ninu re…

 

E TUN LE KA: Ti Mo Pada Ba Ra Arsenal, Maa Le Wenger Da Nu- Aliko Dangote

 

bbnaija-winner-efe-helen-paul-mribu-orisunbbnaija-winner-efe-helen-paul-mribu-orisun