Skip to content

Baba Sala O Tii Ku o,E Ma Da Won Loun O-Omo Baba Sala

Baba sala o kin se alejo si movie industry latari wipe o ti se opolopo ise ribiribi lati gbe industry naa ga ti awon eyan si fi moo. Ni aipe yii ni iroyin n kan kakaakiri wipe aderinposhonu agba yi Moses Olaiya ti gbogbo wa mo si Baba Sala ti ku.

Omo Baba Sala ti jade si gbangba lati so wipe baba sala o tii ku o, o wa laiye lalafia. O so siwaju si wipe iroyin ti o n kan kakaari yii je iroyin ti o ti pe tio si je tooto. ….‘It’s not true. I still spoke to him this morning. This man you’re talking about is my biological father and it’s painful that this kind of thing goes on every time. At least Nigerian journalists should reach out to the family before publishing such stories. Baba Sala is fine and I, his son still spoke to him today.’

E TUN LE KA: Osere Bimbo Thomas Fi Aworan Omo Re Yangan

Looto, Moses Olaiya wa ni idubule aisan teleteleri sugbon o laa koja ti o si n gbe igbe aiye alafiaa. Moses Olaiya  je okan gboogi ninu awon ti n se ere theatre ti o kun fun comedy, drama ati music