Skip to content

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun
Baba gbaju-gbaja osere ‘binrin Mercy Aigbe se alaisi ni ale ana. Osere naa ti o gbe aworan abela si ori ero ayelujara so wipe baba oun ti ku ti o si n s’ofo baba re lowolowo.

E tun le ka: Biodun Okeowo s’oro leyin ti won ji iPhone 7 re
Ti e ba ranti wipe laipe yii ni baba okan ninu awon gbaju-gbaja osere ‘binrin kan naa ti ku.
O gbe aworan kan si ori ero ayelujara ti o si ko si abe re wipe: “Rest on Dad.”