Skip to content

Aya Aare Aisha Buhari Lo Mecca

Aya aare orileede Nigeria, aisha buhari ti lo si mecca, Saudi Arabia ni ojo aje  Monday, August 28, 2017 lati ko pa ninu hajj odun yii… Gegebi, oluranlowo si iyawo aare, Zaynab Ikaz- Kassim se so, aya aare fi abuja airport sile ni ojo aje lati darapo mo awon 20 million eeyan ni mecca.

E TUN LE KA: Mo Ma Mu Buhari Larada Ti O Ba Wa Si Odo Mi- Satguru Maharaj Ji

O so eleyi di mimo lati ori ero ayelujara twitter (@zaykassim) to ti so wipe: “This Afternoon H.E Mrs. aishambuhari left Abuja for Mecca, Saudi Arabia to join millions of muslims in performing this year’s Hajj.”