Skip to content

E Wo Awon Aworan Yii Ti Sir SHINA PETERS Fi Se Ojo Ibi Omo-odun Ogota

E Wo Awon Aworan Yii Ti Sir SHINA PETERS Fi Se Ojo Ibi Omo-odun Ogota

Olorin Gbajumo Nla ti awon eniyan mo si Sir SHINA PETERS ti aye n pe ni Oludasile Afro-Juju music ni gbogbo aye n pe omo odun ogota loni..Inu wa si dun lati baa se ojo ibi naa. Loni ogbon ojo, osu ebibi odun 2018, ojo eye Sir Shina peters ni o gbe awon aworan yii jade lati fi dupe lowo oluwa.

E wo awon aworan naa nisale yii:

Shina-peters-shina-music-birthday-60years-60-old

Shina-peters-shina-music-birthday-60years-60-old

Shina-peters-shina-music-birthday-60years-60-old