Awon osere er agbelewo Yoruba ti won fe arawon nisu loka po gan ni nollywood ti awon fans won o de mo nipa e ti won si n fi igbe aye won si abele….
- Damola Olatunji and Bukola Awoyemi
Ilumooka osere, damola olatunji se igbeyawo pelu bukola awoyemi ti o se ere arugba; ti won sin i ibeji…
- Toyin and Sunday Adewale
Toyin Adewale ti o je okan lara awon osere ti won fen i inu ere sinima Yoruba ni iyawo Sunday adewale ti o je movie director ti o si je osere ninu awon ere Kankan. Ogbeni Sunday adewale naa si je scriptwriter.
Toyin ati Sunday Adewale ni obi olorin Mayorkun
- Lukman Raji and Aminatu Papapa
Bukky Adekogbe ti gbogbo wa mo si aminatu paapaapaa ati lukman raji iyen king of swagga n fe arawon. Awon osere mejeeji fe arawon ni odun melokan seyin ti won sit i bi omo obirin
2. Afeez Eniola and Esther Kalejaye
Eniola Afeez je ilumooka movie producer, osere ati script writer ni idi ere sinima yooba. O darapo mo ise theatre ni odun die seyin pelu atilehin osere bose olubo. Azeez se igbeyawo pelu osere esther kalejaiye ti gbogbo wa mo si omo joyiibo ninu jenifa’s diary ni odun die seyin
- Fausat and Rafiu Balogun
Fausat Balogun ti gbogbo eeyan mo si Madam Saje se igbeyawo pelu osere, scriptwriter ati movie producer Rafiu Balogun. Die ninu awon ti won jo wa ninu industry ni won mop e tokotaya ni won latari bi won se n se ni awujo. Rafiu ati Fausat balogun pade ni idi ise ere sinima ni bi odun gboin seyin, leyin ti osere rafiu ti o je oga madam saje de nu ife ko, ti won si se igbeyawo