Skip to content

Awon Osere Yoruba Ti Won Fera Won, NUMBER 1 MA YA YIN LENU

Awon osere er agbelewo Yoruba ti won fe arawon nisu loka po gan ni nollywood ti awon fans won o de mo nipa e ti won si n fi igbe aye won si abele….

 

  1. Damola Olatunji and Bukola Awoyemi

Ilumooka osere, damola olatunji se igbeyawo pelu bukola awoyemi ti o se ere arugba; ti won sin i ibeji…

damola-OLATUNJI-ORISUN damola-OLATUNJI-ORISUN

  1. Toyin and Sunday Adewale

Toyin Adewale ti o je okan lara awon osere ti won fen i inu ere sinima Yoruba ni iyawo Sunday adewale ti o je movie director ti o si je osere ninu awon ere Kankan. Ogbeni Sunday adewale naa si je scriptwriter.

Toyin ati Sunday Adewale ni obi olorin Mayorkun

 

Sunday-toyin-adewale-orisun

 

mayorkun-orisun

 

  1. Lukman Raji and Aminatu Papapa

Bukky Adekogbe ti gbogbo wa mo si aminatu paapaapaa ati lukman raji iyen king of swagga n fe arawon. Awon osere mejeeji fe arawon ni odun melokan seyin ti won sit i bi omo obirin

 

lukman-raji-orisun lukman-raji-orisun lukman-raji-orisun

 

2.  Afeez Eniola and Esther Kalejaye
Eniola Afeez je ilumooka movie producer, osere ati script writer ni idi ere sinima yooba. O darapo mo ise theatre ni odun die seyin pelu atilehin osere bose olubo. Azeez se igbeyawo pelu osere esther  kalejaiye ti gbogbo wa mo si omo joyiibo ninu jenifa’s diary ni odun die seyin

Eniola-Afeez-orisun    

  1. Fausat and Rafiu Balogun

Fausat Balogun ti gbogbo eeyan mo si Madam Saje se igbeyawo pelu osere, scriptwriter ati movie producer Rafiu Balogun. Die ninu awon ti won jo wa ninu industry ni won mop e tokotaya ni won latari bi won se n se ni awujo. Rafiu ati Fausat balogun pade ni idi ise ere sinima ni bi odun gboin seyin, leyin ti osere rafiu ti o je oga madam saje de nu ife ko, ti won si se igbeyawo

madam-saje-orisun