Awon oloja ti ke Jagbari si Ijoba ni eleka nka lati bawon wa nko se si eto oro aje to denukole.
Awon onisowo kakiri ni oja bi Oshodi, Ojodu sunday market, Ile Epo, ati awon miran lorisirisi ni orilede wa so wipe, owon gogo oja ti mu okuta wo oja wo. Ni tori pe awon ara ilu ko ya si odo won wa ra oja bi won ti lero re.
Fun ekun rere iroyin yi e wo aworan yii
