Skip to content

Ni Ojoru Ikilo Jade Fun Awon Obi Lori Awon Omo Won Ni Ile-Iwe

ikolo fun awon obi- itoju omo

NI OJO OJORU IKILO JADE FUN AWON OBI LORI AWON OMO WON NI ILE-IWE

Ni ojoru, awon igbimo egbe ti o n soju awon ile-iwe Post Primary School Management Board (PPSMB) ti Ilu Enugu, fun awon obi ni imoran wipe ki won fun awon omo won ni abo to peye ni asiko isinmi olojo gbogboro ti won lo fun yii.

Ogbeni Nestor Ugwu, oludari igbimo egbe PPSMB ti awon News Agency ti Nigeria ba ni gbolohun oro ni ilu Enugu wipe, gbigba holiday olojogbogboro kii se fun igbe-aye radarada; Ugwu so wipe awon obi miran ko ni aye lati bojuto awon omo won ni asiko yii.

‘’oni awon obi miran to so wipe awon omo won lo fun eko amo asiko yi je igba ti awon omo miran lo fun ohun biburu.’’

 Gege bi obi, odara la ti lo ma beju wo awon omo wan i ibikibi ti won ba lo ti n gba eko lati fi mo bo ya ohun ti odara ni won se ni be

 ’óbi gbodo ni asiko fun awon omo won’.

Ibi Ti Awon Omo Ileewe Yoo Ti Se Idanwo Jamb Ti odun Yii

Agbudo mo ohun ti n won se; wo ohun ti won se, iru ere ti won n wo.

Eyi se dondon nitori wipe wok o ni di omo buruku siinu ilu to ba ya.

O tun wipe ki awon obi ma bere fun esi idanwo awon omo won, ki asi yin omo ti n ba se dara dara.

ki asi gbein yanju lati so fun eyi to ko se dara dara lati ma ka iwe re

Oludari ajo yi wipe ni won gbati omo eni ba re  wipe aferan awo, won ma di omo re ni inu ilu.

Ugwu wipe Ijoba ilu ti n kede lati mu ileri won se lati ma sun owo awon osese won.

E Le wo fidio miran loke patapata.