Skip to content

Awon Ile Igbimo Asofin So Wipe Ki Won Gbe Iye Epo Petiro Si N150

Nje Nigeria n lo siwaju sii ni abi o n lo seyin? Awon ile igbimo Asofin ti won yan fun gbogbo ise ati ise ni Nigeria ti gbimo lati gbe iye owo epo petiro lati N145 si N150.

Igbimo naa jeki eyi di mimo leyin ti won gbo iroyin lori National Roads Fund (Est. ETC) Iwe Ofin (SB.218) fun awon ti o mo’fin gege bi won ti gbe si’waju Ile Asofin naa.

DINO MELAYE Ti Lo Gba Satifikeeti Re Ni ABU Zaria Ooo. E wo Iye Eniyan To Tu Jade

Gege bi Alaga igbimo naa Ogbeni Kabiru Gaya ti so, Eto owo naa ti won ba le gbee kale, yoo “Je nnkan ti yo gba owo lowo awon ti o n lo oju-ona pelu  awon owo sisan miran lati fi gbe bukata awon oju ona ti o ti baje ni Nigeria.

Lara awon erongba awon Igbimo yi ni wipe ki Ijoba fi kun owo epo; fun keegi tabi lita epo petiro ati disu ti won n gbe wo ile wa ati eyi ti won buro ni Nigeria.

Igbimo naa gbero lati san maa gba owo-ibode; ti o je ida mewa ti awon yoo maa gba lori oko kan ti o n rin loju ona Ijoba.

Siwaju sii, won gbero wipe ki awon Oko ti o maa n jade kuro ni Orile ede Nigeria maa san iye owo kan, beeni ki awon ti o n lo kaakakiri ipinle ati agbegilodo naa ma san die ninu ida kan ti won o maa yo ninu owo ti won gbe awon ero won.

Ninu awon meedogun ti won wa lara igbimo naa, awon sineto ti o fowo si iwe ofin naa ni Sineto Gaya, Clifford Ordia, Barnabas Gemade, Mao Ohuabunwa, Bukar Abba Ibrahim, Ben Bruce, Gilbert Nnaji, Abubakar Kyari, Ibrahim Danbaba, Mustapha Bukar, Sani Mustapha and Buruji Kashamu.

Ni idakeji, Sineto Olusola Adeyeye, Biodun Olujimi and Ahmad Ogembe ko fi owo si iwe naa.

Esi nnkan ti igbimo naa fihan ni won ti pin fun gbogbo awon sineto toku fun ijiroro.

Esi Irufe wo ni eyin n duro de naa?

 

E le wo fidio yii: