Skip to content
  • Iselu

Atiku Abubakar Ka Awon Ile Ise Ti O Je Ti E Ni Nigeria

Ni odun 2014, Igbakeji aare teleteleri, Atiku Abubakar so wipe oun mop e oun ni oun pese ise ju fun awon eeyan ni Nigeria yi. O so eleyi lori ero abanidore twitter re  @atiku nigba ti o n soro nipa awon odo orile ede yi ati pi pese ise fun odo ni Nigeria. “As an individual, I believe my record in employing young Nigerians is unrivalled by any single private investor in Nigeria #LetsTalkJobs.”

E TUN LE KA: Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

Atiku Abubakar ti o ni investments ni inu Media, shipping, education ati awon sectors miran so wipe oun gba eeyan bi 50,000 si ise lowolowo ni inu awon ile ise oun ni Nigeria.  O tun se afihan nla lori ero abanidore twitter re nigba ti eyan kan fi esun kan pe oun lo ni ile ise mikano ti o n se ero amunawa (generator)….

atiku-orisun

Atiku ti iroyin ti n to wa leti n so wipe yoo dije fun ipo aare ni 2019 daa lohun pe iron i o…

atiku-abubakar-response-orisun

Leyin ti o so be, o wa te siwaju lati so awon ile ise ti o je tie:

atiku-abubakar-companies-orisun