E Wo Atejade Egbe PDP Ti O Fihan Wipe Won N Gbimo Lati Fi Ipa Gba Gbogbo Ilu Ekiti
Egbe Oselu (PDP) ti ilu Ekiti ti n f’arasise lati je ki a mo wipe awon yoo fi ipa gba ijoba lowo egbe APC gege bi atejade ti a ri gba. Eyi jade ni ana ode oni lati Ile ijoba asofin ti ilu Ekiti.
Ninu atejade naa ti awon ajo kekere ti won n pe ni National Working Committee so wipe Ijoba-awa’rawa ti wa ninu Igbekun; beeni orile Ede Nigeria ko f’araro labe akoso egbe oselu APC.
Gegebi egbe PDP se ko sita, Adams Oshiomole ti o je alaga-agba fun egbe APC so ni igba ikede fun ibo wipe egbe naa wa lati ba gbogbo ise-egbin ati iwa jegudujera je lai ku eyokan wipe bi ilu Ekiti se ri gba Ijoba ti yoo gba gbogbo agbara.