Skip to content

“Asiri Ti O Wa Leyin Ori Mi To Pa”- Papa Ajasco

Opolopo eeyan ni o feran ere agbelewo Papa Ajasco and Company ti o n je The Ajasco Family te le sugbon gbogbo eeyan ko lo mo asiri ti o wa leyin ori papa ajasco to paje.

Abiodun Ayoyinka ti gbogbo eeyan mo si Papa Ajasco ni o ma n se ere agbelewo ti wale adenuga da sile ni 1996.Ninu iforowanilenu wok an ti o se lai pe yi, Papa Ajasco tu asiri ti o wan i eyin ori re ti o ma n paje ninu ere naa, o ni; “The bald head is not original, it’s fake. Anytime I’m going for my recording, I shave it off, for the past 19-years now. At all, it will not grow. Because I’m so handsome with it.”