#ASIRI: Awon Nnkan Ti E Ko Mo Nipa MERCY Aigbe
Orisun l’agba gege bi a ti mo! Eyi lo mu ki a se agbekale “Mimo awon Gbajumo” lori Orisun fun awon eniyan ti ko mo won.
Lori abala yii ni a ti yannanaa ohun ti awon eniyan le ma mo nipa Gbajumo osere nla nni MERCY AIGBE.
E wo fidio ti o wa loke yii ki e le fi mo asiri naa! ⇑⇑