Arabirin kan ti o mo nipa eekana sise ni Houston texas, Ayanna Williams ti gbe oruko re wo inu iwe Guinness World Records 2018 Edition nitoripe oun lo ni Eekana ti o gun ju ni agbaye (world’s longest fingernails).
E TUN LE KA:Ewo Ere Aderinposhonu Kenny Blaq Lori Miliki Express
Eekana kan kan arabirin Ayanna gun to 2foot, o de gba odun meta le logun (23yrs) lati je ki won gun to yen leyin ti o so wipe ore oun lo fi okan oun si… Gegebi Ayanna ti so, o so wipe oun si ma ma je ki ekana oun gun si , o so wipe o ma gba oun ni bi ose kan lati kun ekana oun ati wipe o ma le fun oun lati wo sokoto bayi.
Lati ripe oun toju ekana oun, Ayanna so wipe oun ma n lo anti bacterial soap ati nail brush lati fi maa foo mo lojoojumo.