Skip to content

ANFANI T’O WA NINU YIYAN ISE THEATRE LAAYO

Ise Theatre je ise ti opo obi fi owo si pe ki awon omo lo se latari opo eniyan ti o ti se orire lati ipase ise na bi Baba Adebayo Faleti, Adebayo Salami, Jide Kosoko, Bukky Wright, Mercy Aigbe, Iyabo Ojo, Odunlade Adekola atibeebeelo. Leyin pe o di Ilumooka, awon anfani wo lotun wa ninu sise ise theatre, e wo ninu fidio yi ni bi ti a tin jiroro lori re….

E TUN LE KA:Mo Ti N Fi Ise Aderinposhonu Pa Owo Lati Ile Iwe- KOFFI

E TUN LE WO: