Skip to content

Awon Anfani Ti O Wa Ninu Rira Bitcoin

Bitcoin je eya owo ti o sese bere sii di gbajumo laarin awujo wa. opo awon oloro ilu wa si lo n lowo ninu nina, lilo ati rira bitcoin. Awon ilu bi america, china ati awon ilu die ni africa n fi bitcoin se ona dinadura ni inu ilu won. Nigeria naa si ti bere si ni da awon eniyan leko lori iwulo Bitcoin, Nkan ti o je ati bi a ti le ra….. Awon nkan yi ni a ro lati fi da awon ololufe orisun leko lori Bitcoin….

E WO LOKE: