Alhaja Otibiya Pe Awon Eniyan Ki Won Ran Awon Odo Lowo
Alhaja Azeezat Lawal pe si awon ti ori se igi ola si ni awujo lati ma ran awon odo ti o ni ebun lowo fun idagba soke ebun won.
Oro yi ni Alhaja Azeezat so ni ibi ayajo Otibiya ti won se ni ojo kejidiniogun osun kejila odun yii. (18/12/2016) ninu gbongan LTV. Ayajo otibiya o hun ni won gbe kale fun awon odo ti o lebun orin pataki julo orin Islam, ti won o si ri eni gbawon jade.
E wo fanran yi fun ekunrere iroyin
