Skip to content

Aisha Buhari Soro Lori Aisan Ti O N Se Mohammadu Buhari

Iyawo Aare Orile ede Nigeria, Arabinrin Aisha Buhari soro loni nipa Ilera ara Muhammadu Buhari lati fi pa awon eniyan buruku lenu mo.

Buhari pada de lati Ilu Oba ni ojo kewa Osu keta lehin Isinmi olojo gbogboro ti o gba lati fi toju ara re.

READ: Fayose Wa Lara Awon Ti Won Ran Ki O Ma Da Ilu Nigeria Ru O – KASHAMU

Lenu Ojo meta yii, Buhari ko jade bii ti tele mo nitori ailera naa.

Nnkan ti a ri gbo lati enu Aisha ni wipe Ko le to bi awon eniyan ti n pee. ‘Lagbara Olorun, ara baba ko ni pe ya’

FIDIO: