Skip to content

Ah! O Bo: IJOBA IPINLE KANO YO MOHAMMAD SANUSI LOYE!

Iroyin lo de si eti igbo wa ni amohunmaworan Orisun wipe, Ijoba Ipinle kano yo Emir ti Ilu Kano, iyen Mohammad Sanusi ni Ipo.

Eyi ni igbese ti won gbe leyin ti won fi esun aigboran ati iselodi si Gomina Ilu Naa, Gomina Abdullahi Umar Ganduje ati awon ofin ilu naa.