Skip to content

Ah Iya Ma Je Mi Ooooo Dufada

Ah Iya  Ma Je Mi Ooooo Dufada

Oluranlowo igbakan ri fun Aare ano Ebele Goodluck Jonathan ti fi esun kan ajo EFCC pe won n lo awon iwe-eri ti kii se oto lati tembelu ohun.
Ogbeni Waripamo-Owei Dudafa soro ni ojo Aje 23 January 2017 fun ile-ejo agba ni Ipinle Eko wip gbogbo oro ati eri ti awon ajo EFCC gba ni owo ohun kii se ojo lasan nitori ara ohun ko dagaji ni igba ti won n ngban ti o si je idi ti o fi ro ejo mo Aare ano Jonathan lese.
O so wipe gbogbo awon igbohun na sele ni igba ti ohun wa latimole ni ahamo EFCC bi o ti n je irora and inira ni opa eyin si won ki fi igba kan mu Dokita wa lati be ohun wo tabi toju ohun.

 

DUFADA

O ni pe awon ajo ti o n ri ibaje na EFCC na ti ogbon alumokoroi je ki ohun bu owo lu awon iwe-eri na dibo jijade laye ati alaafia.
Nigbati o n soro gbogbo ohun ti oju e ri ninu ahamo awon EFCC, Dufada won ko gba ki awon ebi tabi awon ara ohun gbe ounje wa fun tabi se itokuju ohun ti eyi si je ki iya je ohun gan.
Dufada ni lati osu April 27-May 12 2016 je awon igba ti ohun wa iku sugbon ko ri. o so wipe ni igba miitran, won a gbe ohun kuro ni ahamo na si won gbe ohun lo si ile-ise won lati ago meji aro di ago mejo ale (8am-8pm, igbe miira di ago mokanla (11pm) bi idun won ba se dun si ni.
Ailera ti ohun ni ni isin ni je yiye opa-eyin (spinal card discolation). Won ko bi ailera yi mo mi o sugbon ni owo igba ti mo lo ni ahamo won to won de n fiya je mi ni o bere si mi.
Mi o si ni alafia lati le ko oro gidi sugbon won fi ipa je kin n soro. Nitori na gbogbo ate ti o jade yen kii se gidi yala won te jade lati ba mi loruko je.
Lehin igba ti won fi ipa gba oro lenu mi, won ko je ki ri agbejoro i.. Koda nise ni won le agbejoro mi bi aja.
nigbati ailera yen po gidi awon osise EFCC fun ohun ni ogun oyinbo bi Paracetamol ati aspirin.

O so wipe opolopo ayewo ni won se fun ni ile-iwosan, ti won fi ri pe opa eyin e ti ke ti os i nilo lati ri Dokita. O de ni won EFCC ko je ki ohun lo ri Dokita ti won o si gba ki awon ebi ohun mu Dokita wa fun ohun lai le fun ohun ni itoju to ye.

A!! Iya ma je mi o! won fi iya je me debi pe nise ni erru gbogbo awon eniyan to wa lagbegbe mi n ba mi. Iya yi po! won di owo iyawo mi mo banki won se owo ile-iwe awon omo mi na mo banki ki won sa le foro emi mi.
O salaye pe won ko i ipa u ohun lati rojo mo ara ohun lese.

Adajo lori orona, Adajo Mohammed Idris ti sun igbejo na si January 24 lati pari igbejo na.

Lakotan, o ni won fi esun ipadiapopo latti ji owo ijoba ton lobi bilionu nara kan le ni mefa(1.6B) ni ojo kokanla osu kefa odun 2013.