Agbaboolu Orileede Nigeria, Onazi Ogenyi ti bo si ori ero abanidore Instagram re lati fi she afihan awon aworan to rewa ti omo re obirin ti o se bi lai pe yii. Onazi ati Iyawo re Sandra bi omo obirin ni August 1st si oke okun.
Ni inu oro ti o ko si ori ero abanidore instgram re, onazi fi ye w ape oun se tan lati rip e omo oun ni itoju to pe ye atiwipe oun se tan lati se gbogbo nkan ti obi n se fun omo… “The day you came into my life, I knew what my purpose was. To love ❤️ and protect with everything I have. So much love from Daddy. Amore mio. #makayla #emiene #ogenyionazi”