Skip to content

Awon Agbaboolu Nla Ti O Ye K’o Lo Gba RUSSIA 2018

Awon Agbaboolu Nla Ti O Ye K’o Lo Gba RUSSIA 2018

Bi o ti je wipe a ti gbe awon omo jade fun Boolu RUSSIA 2018, awon agbaboolu kookan si wa ti o ye ki won gbe jade fun idije naa. Awon meji ni a o yananaa loni.

Nigeria n yangan wipe awon ni awon egbe agbaboolu ti o kere lojo ori julo; Beeni FIFA so wipe awa ni a gbe awon agbaboolu kekere julo fun ifesewonse fun RUSSIA 2018.

1. Obafemi Martins

Russia-2018-Obafemi-martins-nigerian-super-eagles

The former Inter Milan striker who has been involved with the Super Eagles in time past has been in good form for his Chinese club Shanghai Greenland Shenhua .

Akoko ni Ogbeni Obafemi Martins ti o je Striker fun Inter Milan; ti o si ti wa pelu iko Super Eagles fun igba pipe ti gbaradi fun Club Shanghai re , won si le loo fun Idije Russia 2018 naa sugbon awon omode ni won fe fi dije naa lodun yii. Ni’gbati o fi n gba boolu fun iko naa, o je Goal mejidinlogun.

 

2. Efe Ambrose

efe-ambrose-super-eagles-russia-2018.018c2f98

The Hibernian of Scotland defender was once Super Eagles first choice at right back but he has struggled to make the team since the arrival of the German tactician Gernot Rohr.

Efe Ambrose je eni ti awon adari Iko Super Eagles ko tii gba ti e to sugbon bi won ko se muu lo fun idije naa; o seese ki won pee pada nitori awon ohun ribi ribi ti o ti se seyin. Efe ti gba boolu fun Celtic beeni Henernian ti won si fowo re soya fun ise takuntakun ti o se.