Skip to content

Agbaboolu Kenneth Omeruo De Nu Igbeyawo ko Afesona Re

Agbaboolu fun Super Eagles, Kenneth omeruo ti de nu igbeyawo ko ore obirin re, Chioma Nnamani. O fi fidio idenuko pajawiri naa si ori ero abanidore instagram re….

E TUN LE KA: Rohr pe Alex Iwobi Pada Fun Idije Pelu Zambia

o so wipe; Blessed to have you @oma_maranma ?thank you for accepting me?? and thanks to my people who made it a surprise for real.. @crazeclown @pencilcomedian @romeo_wj ????. Swipe for moreeeee

 

 

E ku orire o!!!!