Skip to content

Ado Oloro Dun Ni Ile Maiduguri Lana o

Ado oloro je nnkan ti o n ba aye je. Lale ana ni ilu Maiduguri ni ikan ti dun lana ode oni bi awon omo iko Boko Haram meji ti a fura si ti gbiyanju ati pa awon ti o gbe ni agbegbe naa legbe Ibudoko kan.

Meji ninu awon ti o n yin ado-oloro yii ni o ku. Ki okan lara won to ku ni o ti ju ta ado na ti o si gbana ni agbegbe Muna Park ni Gariki. Eleekeji ni awon Soja fi ibon fo lese ki o to ta ado tie.

Ki Olorun gba wa lowo awon eniyan Ibi o.