Skip to content

Aare Orile Ede Yi Ti Dagba Ju, Bishop Okah Ni Ki E Gba Omode Laaye

Aare Orile Ede Yi Ti Dagba Ju, Bishop Okah Ni Ki E Gba Omode Laaye. Bishop Okah ti o je Adari agba Ijo Flock of Christ ro aare Mohammadu Buhari pe ki o gbagbe pe oun yoo dije leekan si ni Odun 2019.

Bishop Okah Lana so wipe Aare Mohammadu Buhar ti dagba ju eni ti o le tuko orile ede yii. Beeni o tun yi enu pada lori idi ti won fi mule pe Buhari ni Eni ti o see fokantan ju ti a ba n soro nipa Niger Delta.
“Baba yii ti dagba ju, Agba lagba n je, Emi ti e tun kere legbe Baba. Omo odun Merilelogota ni mi, se e mo wipe O ni awon nnkan ti awon omode isin maa se ti ko ni ye emi funrara mi nitori pe bi won ti ma n ronu yato si tiwa ambeletasi Buhari:
“Lakoko, Buhari ti dagba ju, Leekeji, Ko kawe to. O dun mi de okan nitoripe Aare tel ri Goodluck Jonathan ti o wa lati Iha Guusu ti Orile ede yi. Ote po fun Jonathan sugbon oun naa si gbiyanju tie loto”.
O tesiwaju lati so wipe “Awa ti a maa n Losi oke okun ni won maa n sofun wipe Ibukun ni pe a ni Aare ti o ti kawe gboye agba: PHD, Kini buhari ni yato si pe O ti je Ogagun ri?”
Bishop Okah leekan sii tun dekun Rev. Mbaka ti o gboriyin fun Buhari pe oun ni eni ti o fun Nigeria ni Ominira.
“Lododo, Ooto maa n so ara e, Kini Buhari ti fun ni Ominira, Se Eto isuna wa Abi kini? Nigbati e ba so wipe oun Ni Oludande.. Ki ni O ti dasile?
“Dipo Ki o toju Orile ede yii, O ti jeki o baje sii. O gba Ijoba nigba ti owo dola je 170Naira si 190Dollar sugbon loni Elo ni” Ni nnkan ti Bishop so.
“Nigbati a fe dibo, o n pariwo wipe Oun o so Dola di Naira kan sugbon nibo ni Orile ede yii wa bayi? Gbogbo nnkan ti Jonathan ti to lo ti daru”
READ MORE FROM SOURCE HERE
“When he was campaigning, he said he would make one naira to one dollar, but what is the position today, the man has destroyed almost everything he met, everything Jonathan labored for. Everything is nose-diving in the country.
“Look at the stock exchange. He inherited a stock exchange of over N13 trillion. Today, it is about N8 to N9 trillion. What happened to N4 trillion?
“It is people’s money, so to me, this government, particularly, in my own sense of judgment, there are too many lies and lies go with depression and depression goes with oppression.
“People who are supposed to invest are asking questions, where are the blueprints for his economic programme.? Almost two years are gone, nothing. This is the very first time in our history that it took a president, who won an election over six months to appoint ministers.
“And the people he appointed are the same corrupt people, who had to cross-carpet from PDP to APC; we thought he was going to bring angels from the moon the way he initially spoke about people that would make his cabinet, but finally, they were the same people that we knew in this country.
“As a man from South-South, I feel very bad the way we have been treated. Look at the oil blocks too, how many belong to people from the South-South? in the first place, why should the Nigerian government consider giving oil blocks to individuals instead of state government?
“Why should such huge amount of money go into hands of very few individuals? If we want to build a nation, these are questions that we need to ask,” the Bishop stated.
SOURCE : THE NATION