Skip to content

Aare OnaKakanfo Ba Awon Omode Soro Lati Je Olododo Ninu Ohun Gbogbo

Aare Onakakanfo Ile Yoruba “Gani  Adams” Ba Awon Omode Soro lati je olododo ninu ohun gbogbo ti won nse, O si ba awon Obi Soro lati maa Se Itoju Awon Omo. Iroyin Lekunrere Ree