Aare Muhammed Buhari tun ti fi oruko awon eniyan merin-din-ladota ranse si ile-igbimo-asofin agba lati gbe won yewo, ki won si se imudaju won fun ipo asoju orile-ede Nigeria ni oke okun .
Ninu akojo oruko tuntun na, won ropo oruko lati ipinle metala, ti Ipinle Eko si padanu aye kan.
Akojo oruko na fin han wipe oruko Omo egbe igbimi asofin Alagba Olorunnibe Mamora ko si nibe, ti won si fi Afolayan Adeyemi ropo oruko Alagba Adegboyega Ogunwusi ti o je egbon Ooni Ile-Ife
Ninu akojo oruko ti Aare fi ranse ni October odun 2016, oruko awon eniyan meta lati ilu eko jewo, awon oruko na ni Mamora, Adajo agbati o ti fehin ti George Oguntade ati Iyaafin Modupe Irene.
Amofin igbakanri ati Asoju eto eko ati agbegbe igbakanri fun Dr Kayode Fayemi (Gomina Ilu Ekiti) Dokita Eniola Ajayi ni won fi ropo Ogbeni Ayodele Ayodele ti o wa lati Iyin Ekiti
Awon oruko tuntun na ni Aminu Iyawa lati Adamawa; Baba Jidda, Borno; Prof. Steven Ugba, Benue; Dr. Eniola Ajayi, Ekiti; Ahmed Bamalli, Kaduna; Mohammadu Barade, Kebbi and Suzanne Aderonke, Ogun.
Ati Jacob Daodu, Ondo; Afolahan Adeyemi, Osun; James Dimka, Plateau; SahabiIsa Gada, Sokoto; Alhaji Hassan Ardo, Taraba and Capt. Bala Mariga, Zamfara.
Akojo oruko tuntun ti won yan bi asoju igbimo asofin agba Bukola Saraki se ka ni: Uzoma Emenike (Abia), Aminu Iyawa (Adamawa), Maj-Gen Godwin Umoh (retd) (Akwa Ibom), Christopher Okeke (Anambra), Yusuf Tuggar (Bauchi), Baba Madugu (Bauchi), Stanley Diriyai (Bayelsa) Stephen Ugba (Benue) Baba Jidda (Borno) Etubom Asuquo (Cross River), Frank Efeduma (Delta), Jonah Odo (Ebonyi), Uyagwe Igbe (Edo), Eniola Ajayi (Ekiti), Chris Eze (Enugu), Suleiman Hassan (Gombe), Justice Sylvanus Nsofor (Imo), Amin Dalhatu (Jigawa) ati Ahmed Bamilli (Kaduna).
Awon toku ni Deborah Iliya (Kaduna), Prof. D. Abdulkadir (Kano), Haruna Ungogo (Kano), Justice Isa Dodo (Katsina), Mohammadu Barade (Katsina), Tijani Bande (Kebbi), Prof Y. Aliu (Kogi), Nurudeen Mohammed (Kwara), Prof Mohammed Yisa (Kwara), Justice George Oguntade (Lagos), Modupe Irele (Lagos), Musa Mohammad (Nasarawa), Ahmed Ibeto (Niger), Suzanne Folarin (Ogun), Jacob Daodu (Ondo), Afolahan Adeyemi (Osun), Maj-Gen Ashimiyu Olaniyi (Oyo), James Dmika (Plateau), Haruna Abdullahi (Plateau), Orji Ngofa (Rivers), Sahabi Gada (Sokoto), Kabir Umar (Sokoto) Jika Ado (Taraba), Goni Bura (Yobe), Garba Gajam (Zamfara) Capt Bala Mohammad Mairiga (Zamfara) ati Habbiss Ugbada. (FCT).