Skip to content

Aare Mohammed Buhari Bere Ise Pada

Leyin ti aare buhari gba aye nitori ilera ara re fun 103 days, aare buhari ti pada si enu ise ni olu ilu aso rock. Aare buhari pada si enu ise ni ojo aje Monday august 21,2017, ojo keji ojo ti o bale si ilu abuja ni ojo abameta saturday august 19.

President-Muhammadu-Buhari-orisun

Aare Buhari kede fun isokan nigba ti o ba ara ilu soro ni ojo aje Monday ti o si se ileri lai gbe sukun ijoba le gbogbo awon ti won so oro ikorira ti o ti n sele ni inu ilu ni igba ti ko si ni ile.

E TUN KA: Mo Ma Mu Buhari Larada Ti O Ba Wa Si Odo Mi- Satguru Maharaj Ji

Wakati die si igba ti aare buhari ba awon ara ilu soro, aare buhari ko iwe si ile igbimo asofin (National assembly) lati je ki awon asofin mo nipa bibere ise re leyin igba ti igbakeji aare Yemi Osibanjo da agbara pada si owo aare buhari.

President-Muhammadu-Buhari-with-Vice-President-Yemi-Osinbajo-on-Monday-August-21-2017-orisun

Amugbalegbe aare lori eto ero abanidore, Bashir Ahmad so ni wakati die siwaju wipe aare buhari ma bere sii sise lati ile re titi ti won yoo fi pari atunse si office re.

President-Muhammadu-Buhari-with-Vice-President-Yemi-Osinbajo-orisun