BUHARI SE OJO IBI ODUN KERIN FUN ZEE
Aare orile ede Naijiria, Muhamadu Buhari pelu aya re se ajoyo ayeye ojo ibi kerin fun okan ninu omo-omo won. Oruko omo naa ni Zee.
E o ranti wipe ariyanjiyan kan waye laarin Aare ati Iyawo re, Aisha ni bi osu meji seyin lori ipa ti aare so wipe o n ko ninu ile ohun. A ni gbagbo pe won ti yanju aawo naa.
E TUN KA ELEYI: Oyedepo’s Miracle Described As Fake
A ki Aare ati gbogbo Molebi re, paapaa julo Omode’binrin Zee fun ayeye ojo ibi yi.
Aseyi samodun o.!