Olorin ti o ko orin “Living Things”, Abolore Akande ti gbogbo wa mo si 9ice ti gbe orin tuntun eemi jade pelu oun re ti gbogbo aye n feran, awon orin naa ni Basiri Mi ati Allow.
Awon orin naa ti jade si gbogbo ero abanidore kakaari agbalaaye. Aseorin (producer) Tonywhy ni o po Basiri Mi po ti Aseorin (producer) Olumix po Allow po.
Music Plus:
Basiri Mi: http://mpjamz.com/x/8daac0369