Ben Bruce Ti Gbe Osuba Kare Fun DINO MELAYE Nitori Igbese Ti O Gbe Lo Si PDP
Ogbeni Ben Bruce ti o ni ileese Silverbird ti gbe Osuba Kare fun MELAYE nitori wipe o fi egbe APC sile lo si PDP.
Lana ode oni ni Dino melaye fi egbe APC sile ninu ipade awon igbimo ile Asofin wipe egbe naa ti su oun ti o si gba aaye miran si egbe Are-Egbe naa teleri; iyen Sen. David Mark.
Ben Bruce so ni ede geesi wipe:
Great to have
@dino_melaye at the@NGRSenate today and hearty welcome to our great party,@OfficialPDPNig. We will treat you good – no trauma or intimidation whatsoever.