Igba meje ti Mercy Aigbe ati Omo re gbe ara oge titun yo
Gbaju-gbaja osere ‘binrin Mercy Aigbe ti o ti ni wahala ni ile oko re ati fun bi ose die seyin ti o si ti pinu lati fi oju fo gbogbo rogbo diyan naa, ki o si maa dunu.
E tun le ka: Nkan ti Mercy Aigbe ati omo re Michelle fi jo ara won
E wo awon igba meje ti Mercy Aigbe ati omo re jo jade pelu l’ona ara:
1.
Awon mejeji jo wo aso ti awon oloyinbo n pe ni Jean Jacket lati ile itaja re ti awon mejeeji si n gbadun ibasepo iya ati omo.
2.
Awon mejeeji tun jo gbe ona ara yo ninu aso Oleku.
3.
Iya ati omo tun jo wo aso ti awon oloyinbo n pe ni Monochrome Outfit.
4.
Ibasepo iya ati omo ti a da eniyan l’orun.
5.
Mercy fi best replica rolex ewa omo re Michelle han.
6.
Osere alara naa tun fi ako yo ninu aworan eleyi pelu omo re.
7.
Awon mejeeji tun jo se anko ninu ara oto yii ni ojo ti omo re Michelle pe odun kan.