Skip to content

Awon aworan ayeye igbeyawo omo Bukola Saraki

Awon aworan ayeye igbeyawo omo Bukola Saraki

Alakoso ile-igbimo aare asofin yi ilu Nigeria, Bukola Saraki ati iyawo e Toyin Saraki fi omo won Tosin fun oko ni ona alarinrin ni ojo abameta, ojo ‘kankan le l’ogun, osu k’ewa si Adeniyi Olatunde Olukoya, omo Omooba Tokunbo Olusanya ti Ilorin ni ipinle Kwara.

Tosin, om’odun marun din l’ogbon naa je akobi ninu awon omo merin ti Toyin ati Bukola saraki ni.

Igbeyawo Tosin si oko re, Adeniyi Olatunde Olukoya sele ni ilu Ilorin ni ipinle Kwara ati wipe gege bi eyan kan se so lori ero abanidore ti o n gbe ni ipinle Kwara, paapaa julo won ti awon obirin ati awon ti o wo Aso-Ebi si ita, ti won ko si je ki won wole si ibi ayeye naa.

E tun le ka: Nkan ti iya Fathia Balogun se ki omo re Fathia to j’eyan ninu ise tiata

Awon aworan naa re:

 

 

 

 

Awon aworan lati ibi ayeye igbeyawo alarinrin omo Bukola Saraki